ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 4:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Torí náà, kí o mọ̀ lónìí, kí o sì fi sọ́kàn pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́ lókè ọ̀run àti lórí ilẹ̀ ayé.+ Kò sí ẹlòmíì.+

  • Àìsáyà 44:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ẹ má ṣe jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá yín,

      Ẹ má sì jẹ́ kí ìbẹ̀rù sọ ọkàn yín domi.+

      Ṣebí mo ti sọ fún ẹnì kọ̀ọ̀kan yín ṣáájú, tí mo sì kéde rẹ̀?

      Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi.+

      Ṣé Ọlọ́run kankan wà yàtọ̀ sí mi ni?

      Rárá, kò sí Àpáta míì;+ mi ò mọ ìkankan.’”

  • Máàkù 12:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Akọ̀wé òfin náà sọ fún un pé: “Olùkọ́, ohun tí o sọ dáa, ó sì bá òtítọ́ mu, ‘Ọ̀kan ṣoṣo ni Òun, kò sí ẹlòmíì àfi òun nìkan;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́