Àìsáyà 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+ Àìsáyà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé: “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́! Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+ Ìfihàn 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n kọ orúkọ kan sí iwájú orí rẹ̀, ó jẹ́ àdììtú: “Bábílónì Ńlá, ìyá àwọn aṣẹ́wó+ àti àwọn ohun ìríra ayé.”+
19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+
4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé: “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́! Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+
5 Wọ́n kọ orúkọ kan sí iwájú orí rẹ̀, ó jẹ́ àdììtú: “Bábílónì Ńlá, ìyá àwọn aṣẹ́wó+ àti àwọn ohun ìríra ayé.”+