Àìsáyà 42:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wò ó, àwọn nǹkan àkọ́kọ́ ti ṣẹlẹ̀;Ní báyìí, mò ń kéde àwọn nǹkan tuntun. Kí wọ́n tó rú yọ, mo sọ fún yín nípa wọn.”+ Àìsáyà 65:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí wò ó! Mò ń dá ọ̀run tuntun àti ayé tuntun;+Àwọn ohun àtijọ́ ò ní wá sí ìrántí,Wọn ò sì ní wá sí ọkàn.+
9 Wò ó, àwọn nǹkan àkọ́kọ́ ti ṣẹlẹ̀;Ní báyìí, mò ń kéde àwọn nǹkan tuntun. Kí wọ́n tó rú yọ, mo sọ fún yín nípa wọn.”+
17 Torí wò ó! Mò ń dá ọ̀run tuntun àti ayé tuntun;+Àwọn ohun àtijọ́ ò ní wá sí ìrántí,Wọn ò sì ní wá sí ọkàn.+