Ẹ́sírà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìgbà náà ni Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì àti Jéṣúà+ ọmọ Jèhósádákì bẹ̀rẹ̀ sí í tún ilé Ọlọ́run kọ́,+ èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù; àwọn wòlíì Ọlọ́run wà pẹ̀lú wọn, wọ́n sì ń tì wọ́n lẹ́yìn.+ Àìsáyà 51:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹ,Màá sì fi òjìji ọwọ́ mi bò ọ́,+Kí n lè gbé ọ̀run kalẹ̀, kí n sì fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,+Kí n sì sọ fún Síónì pé, ‘Èèyàn mi ni ọ́.’+ Àìsáyà 66:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Bí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun+ tí mò ń dá ṣe máa dúró níwájú mi,” ni Jèhófà wí, “bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ* yín àti orúkọ yín ṣe máa dúró.”+ 2 Pétérù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ à ń retí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun tó ṣèlérí,+ níbi tí òdodo á máa gbé.+
2 Ìgbà náà ni Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì àti Jéṣúà+ ọmọ Jèhósádákì bẹ̀rẹ̀ sí í tún ilé Ọlọ́run kọ́,+ èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù; àwọn wòlíì Ọlọ́run wà pẹ̀lú wọn, wọ́n sì ń tì wọ́n lẹ́yìn.+
16 Màá fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹ,Màá sì fi òjìji ọwọ́ mi bò ọ́,+Kí n lè gbé ọ̀run kalẹ̀, kí n sì fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,+Kí n sì sọ fún Síónì pé, ‘Èèyàn mi ni ọ́.’+
22 “Bí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun+ tí mò ń dá ṣe máa dúró níwájú mi,” ni Jèhófà wí, “bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ* yín àti orúkọ yín ṣe máa dúró.”+