Òwe 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+
3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+