Àìsáyà 48:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ nítorí orúkọ mi, mi ò ní bínú mọ́;+Nítorí ìyìn mi, màá kó ara mi níjàánu lórí ọ̀rọ̀ rẹ,Mi ò sì ní pa ọ́ run.+
9 Àmọ́ nítorí orúkọ mi, mi ò ní bínú mọ́;+Nítorí ìyìn mi, màá kó ara mi níjàánu lórí ọ̀rọ̀ rẹ,Mi ò sì ní pa ọ́ run.+