ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nehemáyà 9:30, 31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Ọ̀pọ̀ ọdún lo fi mú sùúrù fún wọn,+ o sì ń fi ẹ̀mí rẹ kìlọ̀ fún wọn nípasẹ̀ àwọn wòlíì rẹ, àmọ́ wọn ò gbọ́. Níkẹyìn, o fi wọ́n lé àwọn èèyàn ilẹ̀ tó yí wọn ká lọ́wọ́.+ 31 Nínú àánú ńlá rẹ, o ò pa wọ́n run,+ o ò sì fi wọ́n sílẹ̀, nítorí Ọlọ́run tó ń gba tẹni rò* àti aláàánú ni ọ́.+

  • Sáàmù 78:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Àmọ́, ó jẹ́ aláàánú;+

      Ó máa ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n,* kò sì ní pa wọ́n run.+

      Ó máa ń fawọ́ ìbínú rẹ̀ sẹ́yìn lọ́pọ̀ ìgbà,+

      Kàkà tí ì bá fi jẹ́ kí gbogbo ìbínú rẹ̀ ru.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́