Àìsáyà 45:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Mi ò sọ̀rọ̀ ní ibi tó pa mọ́,+ ní ilẹ̀ tó ṣókùnkùn;Mi ò sọ fún ọmọ* Jékọ́bù pé,‘Ẹ kàn máa wá mi lásán.’* Èmi ni Jèhófà, tó ń sọ ohun tó jẹ́ òdodo, tó sì ń kéde ohun tó tọ́.+
19 Mi ò sọ̀rọ̀ ní ibi tó pa mọ́,+ ní ilẹ̀ tó ṣókùnkùn;Mi ò sọ fún ọmọ* Jékọ́bù pé,‘Ẹ kàn máa wá mi lásán.’* Èmi ni Jèhófà, tó ń sọ ohun tó jẹ́ òdodo, tó sì ń kéde ohun tó tọ́.+