Àìsáyà 44:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Aṣẹ̀dá rẹ àti Ẹni tó dá ọ,+Ẹni tó ràn ọ́ lọ́wọ́ látinú oyún:* ‘Má bẹ̀rù, Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi+Àti ìwọ, Jéṣúrúnì,*+ ẹni tí mo yàn. Àìsáyà 46:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Fetí sí mi, ìwọ ilé Jékọ́bù àti gbogbo ẹ̀yin tó ṣẹ́ kù ní ilé Ísírẹ́lì,+Ẹ̀yin tí mò ń tì lẹ́yìn látìgbà tí a ti bí yín, tí mo sì gbé látinú oyún.+
2 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Aṣẹ̀dá rẹ àti Ẹni tó dá ọ,+Ẹni tó ràn ọ́ lọ́wọ́ látinú oyún:* ‘Má bẹ̀rù, Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi+Àti ìwọ, Jéṣúrúnì,*+ ẹni tí mo yàn.
3 “Fetí sí mi, ìwọ ilé Jékọ́bù àti gbogbo ẹ̀yin tó ṣẹ́ kù ní ilé Ísírẹ́lì,+Ẹ̀yin tí mò ń tì lẹ́yìn látìgbà tí a ti bí yín, tí mo sì gbé látinú oyún.+