Àìsáyà 40:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+ Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+ Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+ Àìsáyà 59:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Wò ó! Ọwọ́ Jèhófà kò kúrú jù láti gbani là,+Bẹ́ẹ̀ ni etí rẹ̀ kò di* tí kò fi lè gbọ́.+
28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+ Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+ Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+