Ẹ́kísódù 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ni Mósè bá na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;+ Jèhófà sì mú kí atẹ́gùn líle fẹ́ wá láti ìlà oòrùn ní gbogbo òru yẹn, ó sì bi òkun náà sẹ́yìn. Ó mú kí ìsàlẹ̀ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ,+ omi náà sì pínyà.+ Ẹ́kísódù 14:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gba orí ilẹ̀ kọjá láàárín òkun,+ omi náà sì dà bí ògiri ní apá ọ̀tún àti ní apá òsì wọn.+ Sáàmù 106:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;Ó mú wọn gba ìsàlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni gba aṣálẹ̀* kọjá;+ Àìsáyà 51:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣebí ìwọ lo mú kí òkun gbẹ, alagbalúgbú omi inú ibú?+ Ṣebí ìwọ lo sọ ibú òkun di ọ̀nà, tí àwọn tí a tún rà gbà sọdá?+
21 Ni Mósè bá na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;+ Jèhófà sì mú kí atẹ́gùn líle fẹ́ wá láti ìlà oòrùn ní gbogbo òru yẹn, ó sì bi òkun náà sẹ́yìn. Ó mú kí ìsàlẹ̀ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ,+ omi náà sì pínyà.+
29 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gba orí ilẹ̀ kọjá láàárín òkun,+ omi náà sì dà bí ògiri ní apá ọ̀tún àti ní apá òsì wọn.+
9 Ó bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;Ó mú wọn gba ìsàlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni gba aṣálẹ̀* kọjá;+ Àìsáyà 51:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣebí ìwọ lo mú kí òkun gbẹ, alagbalúgbú omi inú ibú?+ Ṣebí ìwọ lo sọ ibú òkun di ọ̀nà, tí àwọn tí a tún rà gbà sọdá?+
10 Ṣebí ìwọ lo mú kí òkun gbẹ, alagbalúgbú omi inú ibú?+ Ṣebí ìwọ lo sọ ibú òkun di ọ̀nà, tí àwọn tí a tún rà gbà sọdá?+