Sáàmù 87:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Màá ka Ráhábù+ àti Bábílónì mọ́ àwọn tó mọ̀ mí;*Filísíà àti Tírè nìyí, pẹ̀lú Kúṣì. Àwọn èèyàn á sọ pé: “Ẹni yìí ni a bí níbẹ̀.” Sáàmù 89:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 O ti ṣẹ́gun Ráhábù+ pátápátá bí ẹni tí wọ́n pa.+ O ti fi apá rẹ tó lágbára tú àwọn ọ̀tá rẹ ká.+ Àìsáyà 30:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí ìrànlọ́wọ́ Íjíbítì ò wúlò rárá.+ Torí náà, mo pe ẹni yìí ní: “Ráhábù,+ tó jókòó jẹ́ẹ́.”
4 Màá ka Ráhábù+ àti Bábílónì mọ́ àwọn tó mọ̀ mí;*Filísíà àti Tírè nìyí, pẹ̀lú Kúṣì. Àwọn èèyàn á sọ pé: “Ẹni yìí ni a bí níbẹ̀.”