- 
	                        
            
            Jeremáyà 23:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 “Ẹ gbé, ẹ̀yin olùṣọ́ àgùntàn tó ń pa àwọn àgùntàn ibi ìjẹko mi run, tí ẹ sì ń tú wọn ká!” ni Jèhófà wí.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ìsíkíẹ́lì 34:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Wọ́n wá fọ́n ká torí kò sí olùṣọ́ àgùntàn;+ wọ́n fọ́n ká, wọ́n sì di oúnjẹ fún gbogbo ẹran inú igbó. 
 
-