- 
	                        
            
            Àìsáyà 62:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Àmọ́ wọ́n máa pè ọ́ ní Inú Mi Dùn sí I,+ Wọ́n sì máa pe ilẹ̀ rẹ ní Èyí Tí A Gbé Níyàwó. Torí inú Jèhófà máa dùn sí ọ, Ilẹ̀ rẹ sì máa dà bí èyí tí a gbé níyàwó. 
 
-