Ìdárò 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó ń sunkún pẹ̀rẹ̀pẹ̀rẹ̀ ní òru,+ omijé sì ń dà ní ojú rẹ̀. Kò sí ìkankan nínú gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ tó máa tù ú nínú.+ Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ti dà á;+ wọ́n ti di ọ̀tá rẹ̀. Ìdárò 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Síónì ti tẹ́ ọwọ́ rẹ̀;+ kò ní ẹni tó máa tù ú nínú. Gbogbo àwọn tó yí Jékọ́bù ká ni Jèhófà ti pàṣẹ fún pé kí wọ́n máa bá a ṣọ̀tá.+ Jerúsálẹ́mù ti di ohun ìríra sí wọn.+
2 Ó ń sunkún pẹ̀rẹ̀pẹ̀rẹ̀ ní òru,+ omijé sì ń dà ní ojú rẹ̀. Kò sí ìkankan nínú gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ tó máa tù ú nínú.+ Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ti dà á;+ wọ́n ti di ọ̀tá rẹ̀.
17 Síónì ti tẹ́ ọwọ́ rẹ̀;+ kò ní ẹni tó máa tù ú nínú. Gbogbo àwọn tó yí Jékọ́bù ká ni Jèhófà ti pàṣẹ fún pé kí wọ́n máa bá a ṣọ̀tá.+ Jerúsálẹ́mù ti di ohun ìríra sí wọn.+