Àìsáyà 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+ Àìsáyà 65:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ìkookò àti ọ̀dọ́ àgùntàn máa jẹun pa pọ̀,Kìnnìún máa jẹ pòròpórò bí akọ màlúù,+Erùpẹ̀ sì ni ejò á máa jẹ. Wọn ò ní ṣe ìpalára kankan, wọn ò sì ní fa ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,”+ ni Jèhófà wí.
9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+
25 Ìkookò àti ọ̀dọ́ àgùntàn máa jẹun pa pọ̀,Kìnnìún máa jẹ pòròpórò bí akọ màlúù,+Erùpẹ̀ sì ni ejò á máa jẹ. Wọn ò ní ṣe ìpalára kankan, wọn ò sì ní fa ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,”+ ni Jèhófà wí.