ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 7:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní báyìí, sọ fún Dáfídì ìránṣẹ́ mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Mo mú ọ láti ibi ìjẹko, pé kí o má da agbo ẹran mọ́,+ kí o lè wá di aṣáájú àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+

  • 2 Sámúẹ́lì 7:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ilé rẹ àti ìjọba rẹ máa fẹsẹ̀ múlẹ̀ títí láé níwájú rẹ; ìtẹ́ rẹ á sì fìdí múlẹ̀ títí láé.”’”+

  • 2 Sámúẹ́lì 23:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ǹjẹ́ kì í ṣe bí ilé mi ṣe rí nìyẹn lójú Ọlọ́run?

      Torí ó ti bá mi dá májẹ̀mú ayérayé,+

      Tó wà létòlétò, tó sì wà lábẹ́ ààbò.

      Nítorí ó jẹ́ ìgbàlà mi látòkèdélẹ̀ àti gbogbo ìdùnnú mi,

      Ǹjẹ́ kì í ṣe ìdí tó fi ń mú kó gbilẹ̀+ nìyẹn?

  • Sáàmù 89:28, 29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Èmi yóò máa fi ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ hàn sí i títí láé,+

      Májẹ̀mú tí mo bá a dá kò sì ní yẹ̀ láé.+

      29 Màá fìdí àwọn ọmọ* rẹ̀ múlẹ̀ títí láé,

      Màá sì mú kí ìtẹ́ rẹ̀ wà títí lọ bí ọ̀run.+

  • Jeremáyà 33:25, 26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Bí mo ṣe fìdí májẹ̀mú mi nípa ọ̀sán àti òru múlẹ̀+ àti òfin* nípa ọ̀run àti ayé,+ 26 bẹ́ẹ̀ ni mi ò jẹ́ kọ àtọmọdọ́mọ* Jékọ́bù àti ti Dáfídì ìránṣẹ́ mi, kí n bàa lè máa mú lára ọmọ* rẹ̀ láti jẹ́ alákòóso lórí àtọmọdọ́mọ* Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù. Nítorí màá kó àwọn tó wà ní oko ẹrú lára wọn jọ,+ màá sì ṣàánú wọn.’”+

  • Ìṣe 13:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Bí Ó ṣe jí i dìde nínú ikú, tí kò sì jẹ́ kó pa dà sí ara tó lè díbàjẹ́ mọ́, ó sọ ọ́ lọ́nà yìí pé: ‘Màá fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí mo ṣèlérí fún Dáfídì hàn sí ọ, èyí tó jẹ́ òtítọ́.’*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́