Àìsáyà 41:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Màá gbin igi kédárì sínú aṣálẹ̀,Màá gbin igi bọn-ọ̀n-ní, igi mátílì àti igi ahóyaya síbẹ̀.+ Màá gbin igi júnípà sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú,Pẹ̀lú igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì,+ Àìsáyà 60:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀dọ̀ rẹ ni ògo Lẹ́bánónì máa wá,+Igi júnípà, igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì lẹ́ẹ̀kan náà,+Láti ṣe ibi mímọ́ mi lọ́ṣọ̀ọ́;Màá ṣe ibi tí ẹsẹ̀ mi wà lógo.+
19 Màá gbin igi kédárì sínú aṣálẹ̀,Màá gbin igi bọn-ọ̀n-ní, igi mátílì àti igi ahóyaya síbẹ̀.+ Màá gbin igi júnípà sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú,Pẹ̀lú igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì,+ Àìsáyà 60:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀dọ̀ rẹ ni ògo Lẹ́bánónì máa wá,+Igi júnípà, igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì lẹ́ẹ̀kan náà,+Láti ṣe ibi mímọ́ mi lọ́ṣọ̀ọ́;Màá ṣe ibi tí ẹsẹ̀ mi wà lógo.+
13 Ọ̀dọ̀ rẹ ni ògo Lẹ́bánónì máa wá,+Igi júnípà, igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì lẹ́ẹ̀kan náà,+Láti ṣe ibi mímọ́ mi lọ́ṣọ̀ọ́;Màá ṣe ibi tí ẹsẹ̀ mi wà lógo.+