-
Àìsáyà 58:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Tí o kò bá wá* ire ara rẹ* ní ọjọ́ mímọ́ mi, nítorí Sábáàtì,+
Tí o sì pe Sábáàtì ní ohun tó ń múnú ẹni dùn gidigidi, ọjọ́ mímọ́ Jèhófà, ọjọ́ tó yẹ ká ṣe lógo,+
Tí o sì ṣe é lógo dípò kí o máa wá ire ara rẹ, kí o sì máa sọ ọ̀rọ̀ tí kò nítumọ̀,
14 Nígbà náà, inú rẹ máa dùn gidigidi torí Jèhófà,
Màá sì mú kí o gun àwọn ibi tó ga ní ayé.+
-