-
Nehemáyà 13:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ní àkókò yẹn, mo rí àwọn èèyàn ní Júdà tí wọ́n ń fún wáìnì ní Sábáàtì,+ tí wọ́n ń kó òkìtì ọkà wá, tí wọ́n sì ń dì wọ́n lé kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, wọ́n ń kó wáìnì, èso àjàrà àti ọ̀pọ̀tọ́ pẹ̀lú oríṣiríṣi ẹrù wá sí Jerúsálẹ́mù ní ọjọ́ Sábáàtì.+ Torí náà, mo kìlọ̀ fún wọn pé kí wọ́n má ta nǹkan kan lọ́jọ́ náà.*
-