Àìsáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọ̀pọ̀ èèyàn máa lọ, wọ́n á sì sọ pé: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+ Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.”+ Torí òfin* máa jáde láti Síónì,Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù.+ Míkà 4:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè máa lọ, wọ́n á sì sọ pé: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+ Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.” Torí òfin* máa jáde láti Síónì,Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù. Sekaráyà 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Èmi yóò pa dà sí Síónì,+ èmi yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ wọ́n á máa pe Jerúsálẹ́mù ní ìlú òtítọ́,*+ wọ́n á sì máa pe òkè Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ní òkè mímọ́.’”+
3 Ọ̀pọ̀ èèyàn máa lọ, wọ́n á sì sọ pé: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+ Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.”+ Torí òfin* máa jáde láti Síónì,Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù.+
2 Ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè máa lọ, wọ́n á sì sọ pé: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+ Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.” Torí òfin* máa jáde láti Síónì,Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù.
3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Èmi yóò pa dà sí Síónì,+ èmi yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ wọ́n á máa pe Jerúsálẹ́mù ní ìlú òtítọ́,*+ wọ́n á sì máa pe òkè Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ní òkè mímọ́.’”+