ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 5:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Àwọn akọni nídìí ọtí mímu gbé

      Àti àwọn tó mọ àdàlù ọtí ṣe dáadáa,+

  • Àìsáyà 28:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Àwọn yìí náà ṣìnà torí wáìnì;

      Ohun mímu wọn tó ní ọtí ń mú kí wọ́n ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́,

      Àlùfáà àti wòlíì ti ṣìnà torí ọtí;

      Wáìnì ò jẹ́ kí wọ́n mọ nǹkan tí wọ́n ń ṣe,

      Ọtí wọn sì ń jẹ́ kí wọ́n ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́;

      Ìran wọn ń mú kí wọ́n ṣìnà,

      Wọ́n sì ń kọsẹ̀ nínú ìdájọ́.+

  • Hósíà 4:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ìṣekúṣe* àti wáìnì àti wáìnì tuntun

      Máa ń mú èrò rere kúrò lọ́kàn ẹni.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́