-
Ìsíkíẹ́lì 13:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 “‘Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “‘Torí ẹ ti parọ́ tí ẹ sì ń rí ìran èké, mo kẹ̀yìn sí yín,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”+
-