Jeremáyà 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bí omi tútù ṣe máa ń wà nínú àmù,*Bẹ́ẹ̀ ni ìwà burúkú ṣe wà nínú ìlú yìí. Ìwà ipá àti ìparun ni ìròyìn tí à ń gbọ́ nínú rẹ̀;+Àìsàn àti àjálù ni mò ń rí níbẹ̀ nígbà gbogbo. Míkà 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìwà ipá kún ọwọ́ àwọn ọlọ́rọ̀ rẹ̀,Òpùrọ́ ni àwọn tó ń gbé inú rẹ̀;+Ahọ́n wọn ń tanni jẹ.+
7 Bí omi tútù ṣe máa ń wà nínú àmù,*Bẹ́ẹ̀ ni ìwà burúkú ṣe wà nínú ìlú yìí. Ìwà ipá àti ìparun ni ìròyìn tí à ń gbọ́ nínú rẹ̀;+Àìsàn àti àjálù ni mò ń rí níbẹ̀ nígbà gbogbo.