Sáàmù 82:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Títí dìgbà wo ni ẹ ó máa fi àìṣòdodo dá ẹjọ́,+Tí ẹ ó sì máa ṣe ojúsàájú àwọn ẹni burúkú?+ (Sélà) Hábákúkù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Òfin kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ mọ́,Kò sì sí ìdájọ́ òdodo rárá. Torí àwọn ẹni ibi yí olódodo ká;Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń yí ìdájọ́ po.+
4 Òfin kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ mọ́,Kò sì sí ìdájọ́ òdodo rárá. Torí àwọn ẹni ibi yí olódodo ká;Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń yí ìdájọ́ po.+