ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 29:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Kí o fi ọmọ àgbò kan rúbọ ní àárọ̀, kí o sì fi ọmọ àgbò kejì rúbọ ní ìrọ̀lẹ́.*+

  • Ẹ́kísódù 29:42
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Kí ẹ máa rú ẹbọ sísun yìí nígbà gbogbo jálẹ̀ àwọn ìran yín ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé níwájú Jèhófà, níbi tí màá ti pàdé yín láti bá yín sọ̀rọ̀.+

  • Àìsáyà 56:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ní ti àwọn àjèjì tó fara mọ́ Jèhófà láti máa ṣe ìránṣẹ́ fún un,

      Láti nífẹ̀ẹ́ orúkọ Jèhófà,+

      Kí wọ́n sì di ìránṣẹ́ rẹ̀,

      Gbogbo àwọn tó ń pa Sábáàtì mọ́, tí wọn ò sì kẹ́gàn rẹ̀,

      Tí wọ́n ń rọ̀ mọ́ májẹ̀mú mi,

       7 Màá tún mú wọn wá sí òkè mímọ́ mi,+

      Màá sì mú kí wọ́n máa yọ̀ nínú ilé àdúrà mi.

      Màá tẹ́wọ́ gba odindi ẹbọ sísun wọn àtàwọn ẹbọ wọn lórí pẹpẹ mi.

      Torí a ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà fún gbogbo èèyàn.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́