Àìsáyà 1:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Màá dá àwọn adájọ́ rẹ pa dà sí bí wọ́n ṣe wà níbẹ̀rẹ̀,Àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ á sì rí bíi ti ìbẹ̀rẹ̀.+ Lẹ́yìn èyí, wọ́n máa pè ọ́ ní Ìlú Òdodo, Ìlú Olóòótọ́.+ Àìsáyà 32:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Wò ó! Ọba+ kan máa jẹ fún òdodo,+Àwọn ìjòyè sì máa ṣàkóso fún ìdájọ́ òdodo.
26 Màá dá àwọn adájọ́ rẹ pa dà sí bí wọ́n ṣe wà níbẹ̀rẹ̀,Àwọn agbani-nímọ̀ràn rẹ á sì rí bíi ti ìbẹ̀rẹ̀.+ Lẹ́yìn èyí, wọ́n máa pè ọ́ ní Ìlú Òdodo, Ìlú Olóòótọ́.+