Sáàmù 36:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ọ̀dọ̀ rẹ ni orísun ìyè wà;+Ipasẹ̀ ìmọ́lẹ̀ rẹ ni a fi lè rí ìmọ́lẹ̀.+ Àìsáyà 60:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 60 “Dìde, ìwọ obìnrin,+ tan ìmọ́lẹ̀, torí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé. Ògo Jèhófà ń tàn sára rẹ.+ Ìfihàn 21:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìlú náà ò nílò kí oòrùn tàbí òṣùpá tàn sórí rẹ̀, torí ògo Ọlọ́run mú kó mọ́lẹ̀ rekete,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì ni fìtílà rẹ̀.+ Ìfihàn 22:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, ilẹ̀ ò ní ṣú mọ́,+ wọn ò sì nílò ìmọ́lẹ̀ fìtílà tàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùn, torí pé Jèhófà* Ọlọ́run máa tan ìmọ́lẹ̀ sórí wọn,+ wọ́n sì máa jọba títí láé àti láéláé.+
23 Ìlú náà ò nílò kí oòrùn tàbí òṣùpá tàn sórí rẹ̀, torí ògo Ọlọ́run mú kó mọ́lẹ̀ rekete,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì ni fìtílà rẹ̀.+
5 Bákan náà, ilẹ̀ ò ní ṣú mọ́,+ wọn ò sì nílò ìmọ́lẹ̀ fìtílà tàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùn, torí pé Jèhófà* Ọlọ́run máa tan ìmọ́lẹ̀ sórí wọn,+ wọ́n sì máa jọba títí láé àti láéláé.+