-
Àìsáyà 44:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ẹni tó ń mú kí ọ̀rọ̀ ìránṣẹ́ rẹ̀ ṣẹ,
Tó sì ń mú àsọtẹ́lẹ̀ àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀ ṣẹ délẹ̀délẹ̀;+
Ẹni tó ń sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé, ‘Wọ́n máa gbé inú rẹ̀’+
Àti nípa àwọn ìlú Júdà pé, ‘Wọ́n máa tún wọn kọ́,+
Màá sì mú kí àwọn ibi tó ti dahoro níbẹ̀ pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀’;+
-