ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nehemáyà 6:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Nígbà tí wọ́n sọ fún Sáńbálátì, Tòbáyà+ àti Géṣémù ọmọ ilẹ̀ Arébíà+ pẹ̀lú àwọn ọ̀tá wa yòókù pé mo ti tún ògiri náà kọ́+ àti pé kò sí àlàfo kankan tó ṣẹ́ kù lára rẹ̀ (bó tilẹ̀ jẹ́ pé títí di àkókò yẹn, mi ò tíì gbé ilẹ̀kùn sí àwọn ẹnubodè),+

  • Émọ́sì 9:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 ‘Ní ọjọ́ yẹn, màá gbé àtíbàbà* Dáfídì+ tó ti wó dìde,

      Màá sì tún àwọn àlàfo rẹ̀* ṣe,

      Màá tún àwókù rẹ̀ kọ́;

      Màá tún un kọ́, á sì rí bíi ti tẹ́lẹ̀,+

  • Émọ́sì 9:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Màá kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì tó wà ní ìgbèkùn pa dà,+

      Wọ́n á tún àwọn ìlú tó ti di ahoro kọ́, wọ́n á sì máa gbé inú wọn;+

      Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n á sì mu wáìnì wọn,+

      Wọ́n á ṣe ọgbà, wọ́n á sì jẹ èso wọn.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́