Àìsáyà 49:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àwọn ọba máa di olùtọ́jú rẹ,+Àwọn ọmọ wọn obìnrin sì máa di alágbàtọ́ rẹ. Wọ́n máa tẹrí ba fún ọ, wọ́n á sì dojú bolẹ̀,+Wọ́n máa lá iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ rẹ,+Wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà;Ojú ò ní ti àwọn tó bá gbẹ́kẹ̀ lé mi.”+ Àìsáyà 60:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ẹnubodè rẹ máa wà ní ṣíṣí nígbà gbogbo;+Wọn ò ní tì wọ́n ní ọ̀sán tàbí ní òru,Láti mú ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè wá sọ́dọ̀ rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣáájú.+
23 Àwọn ọba máa di olùtọ́jú rẹ,+Àwọn ọmọ wọn obìnrin sì máa di alágbàtọ́ rẹ. Wọ́n máa tẹrí ba fún ọ, wọ́n á sì dojú bolẹ̀,+Wọ́n máa lá iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ rẹ,+Wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà;Ojú ò ní ti àwọn tó bá gbẹ́kẹ̀ lé mi.”+
11 Àwọn ẹnubodè rẹ máa wà ní ṣíṣí nígbà gbogbo;+Wọn ò ní tì wọ́n ní ọ̀sán tàbí ní òru,Láti mú ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè wá sọ́dọ̀ rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣáájú.+