Àìsáyà 55:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ wá Jèhófà nígbà tí ẹ lè rí i.+ Ẹ pè é nígbà tó wà nítòsí.+ 7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+
6 Ẹ wá Jèhófà nígbà tí ẹ lè rí i.+ Ẹ pè é nígbà tó wà nítòsí.+ 7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+