-
1 Àwọn Ọba 22:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Jèhóṣáfátì+ ọmọ Ásà di ọba lórí Júdà ní ọdún kẹrin Áhábù ọba Ísírẹ́lì.
-
-
2 Àwọn Ọba 12:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Àmọ́ kò mú àwọn ibi gíga+ kúrò, àwọn èèyàn náà ṣì ń rúbọ, wọ́n sì ń mú ẹbọ rú èéfín ní àwọn ibi gíga.
-