Diutarónómì 6:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni kí o máa bẹ̀rù,+ òun ni kí o máa sìn,+ orúkọ rẹ̀ sì ni kí o máa fi búra.+