Àìsáyà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ má ṣe mú àwọn ọrẹ ọkà tí kò ní láárí wá mọ́. Tùràrí yín ń rí mi lára.+ Àwọn òṣùpá tuntun,+ sábáàtì+ àti pípe àpéjọ,+Mi ò lè fara da bí ẹ ṣe ń pidán,+ tí ẹ sì tún ń ṣe àpéjọ ọlọ́wọ̀.
13 Ẹ má ṣe mú àwọn ọrẹ ọkà tí kò ní láárí wá mọ́. Tùràrí yín ń rí mi lára.+ Àwọn òṣùpá tuntun,+ sábáàtì+ àti pípe àpéjọ,+Mi ò lè fara da bí ẹ ṣe ń pidán,+ tí ẹ sì tún ń ṣe àpéjọ ọlọ́wọ̀.