Léfítíkù 11:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bákan náà ni ẹlẹ́dẹ̀,+ torí pátákò rẹ̀ là, ó sì ní àlàfo, àmọ́ kì í jẹ àpọ̀jẹ. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín. 8 Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ èyíkéyìí nínú ẹran wọn, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fara kan òkú wọn. Aláìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fún yín.+ Àìsáyà 65:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wọ́n jókòó sáàárín àwọn sàréè,+Wọ́n sì sun àwọn ibi tó pa mọ́* mọ́jú,Wọ́n ń jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀,+Omi àwọn nǹkan tó ń ríni lára* sì wà nínú àwọn ohun èlò wọn.+
7 Bákan náà ni ẹlẹ́dẹ̀,+ torí pátákò rẹ̀ là, ó sì ní àlàfo, àmọ́ kì í jẹ àpọ̀jẹ. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín. 8 Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ èyíkéyìí nínú ẹran wọn, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fara kan òkú wọn. Aláìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fún yín.+
4 Wọ́n jókòó sáàárín àwọn sàréè,+Wọ́n sì sun àwọn ibi tó pa mọ́* mọ́jú,Wọ́n ń jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀,+Omi àwọn nǹkan tó ń ríni lára* sì wà nínú àwọn ohun èlò wọn.+