7 Bákan náà ni ẹlẹ́dẹ̀,+ torí pátákò rẹ̀ là, ó sì ní àlàfo, àmọ́ kì í jẹ àpọ̀jẹ. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín. 8 Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ èyíkéyìí nínú ẹran wọn, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fara kan òkú wọn. Aláìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fún yín.+
17 Àwọn tó ń sọ ara wọn di mímọ́, tí wọ́n sì ń wẹ ara wọn láti wọnú àwọn ọgbà,*+ tí wọ́n ń tẹ̀ lé ẹni tó wà ní àárín, àwọn tó ń jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀,+ àwọn ohun ìríra àti eku,+ gbogbo wọn jọ máa wá sí òpin wọn,” ni Jèhófà wí.