-
Jẹ́nẹ́sísì 10:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ó di ọdẹ alágbára tó ń ta ko Jèhófà. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi máa ń sọ pé: “Bíi Nímírọ́dù ọdẹ alágbára tó ta ko Jèhófà.”