ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 17:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ọba Ásíríà ya wọ gbogbo ilẹ̀ náà, ó wá sí Samáríà, ọdún mẹ́ta ló sì fi dó tì í.

  • 2 Àwọn Ọba 18:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ní ọdún kẹrin Ọba Hẹsikáyà, ìyẹn ní ọdún keje Hóṣéà+ ọmọ Élà ọba Ísírẹ́lì, Ṣálímánésà ọba Ásíríà wá gbéjà ko Samáríà, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í dó tì í.+ 10 Wọ́n gbà á+ ní òpin ọdún mẹ́ta; ní ọdún kẹfà Hẹsikáyà, ìyẹn ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà ọba Ísírẹ́lì, wọ́n gba Samáríà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́