-
Ẹ́kísódù 14:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Fáráò yóò wá sọ nípa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ṣe ni wọ́n ń rìn gbéregbère káàkiri ilẹ̀. Wọ́n ti há sí aginjù.’
-
-
Ẹ́kísódù 14:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àwọn ará Íjíbítì wá ń lépa wọn,+ gbogbo ẹṣin tó ń fa kẹ̀kẹ́ Fáráò àti àwọn agẹṣin rẹ̀ àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sì fẹ́rẹ̀ẹ́ lé wọn bá nígbà tí wọ́n pàgọ́ sẹ́gbẹ̀ẹ́ òkun, nítòsí Píháhírótì, tí wọ́n ti dojú kọ Baali-séfónì.
-