ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Rúùtù 4:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ìgbà náà ni àwọn obìnrin tó wà ládùúgbò fún ọmọ náà ní orúkọ. Wọ́n sọ pé, “Náómì ti ní ọmọkùnrin kan.” Wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní Óbédì.+ Òun ló wá bí Jésè,+ bàbá Dáfídì.

  • 1 Sámúẹ́lì 17:58
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 58 Sọ́ọ̀lù wá sọ fún un pé: “Ọmọ ta ni ọ́, ìwọ ọmọdékùnrin yìí?” Dáfídì fèsì pé: “Ọmọ Jésè  + ìránṣẹ́ rẹ ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ni.”+

  • Mátíù 1:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Ìwé ìtàn* nípa Jésù Kristi,* ọmọ Dáfídì,+ ọmọ Ábúráhámù:+

  • Mátíù 1:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Jésè bí Dáfídì+ ọba.

      Ìyàwó Ùráyà bí Sólómọ́nì+ fún Dáfídì;

  • Lúùkù 3:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọ

      Jósẹ́fù,+

      ọmọ Hélì,

  • Lúùkù 3:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 ọmọ Jésè,+

      ọmọ Óbédì,+

      ọmọ Bóásì,+

      ọmọ Sálímọ́nì,+

      ọmọ Náṣónì, +

  • Ìṣe 13:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Lẹ́yìn tó mú un kúrò, ó gbé Dáfídì dìde láti jẹ́ ọba wọn,+ ẹni tó jẹ́rìí nípa rẹ̀, tó sì sọ pé: ‘Mo ti rí Dáfídì ọmọ Jésè,+ ẹni tí ọkàn mi fẹ́;+ yóò ṣe gbogbo ohun tí mo fẹ́.’ 23 Gẹ́gẹ́ bí ìlérí tó ṣe, látọ̀dọ̀ ọmọ* ọkùnrin yìí ni Ọlọ́run ti mú olùgbàlà wá fún Ísírẹ́lì, ìyẹn Jésù.+

  • Róòmù 15:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Àìsáyà tún sọ pé: “Gbòǹgbò Jésè yóò wà,+ ẹni tó máa dìde láti ṣàkóso àwọn orílẹ̀-èdè;+ òun ni àwọn orílẹ̀-èdè yóò ní ìrètí nínú rẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́