Hósíà 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní ọjọ́ yẹn, màá bá àwọn ẹran inú igbó dá májẹ̀mú nítorí wọn,+Màá sì bá àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti ohun tó ń rákò lórí ilẹ̀ dá májẹ̀mú;+Màá mú ọfà* àti idà àti ogun kúrò ní ilẹ̀ náà,+Màá sì jẹ́ kí wọ́n dùbúlẹ̀* ní ààbò.+
18 Ní ọjọ́ yẹn, màá bá àwọn ẹran inú igbó dá májẹ̀mú nítorí wọn,+Màá sì bá àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti ohun tó ń rákò lórí ilẹ̀ dá májẹ̀mú;+Màá mú ọfà* àti idà àti ogun kúrò ní ilẹ̀ náà,+Màá sì jẹ́ kí wọ́n dùbúlẹ̀* ní ààbò.+