Sekaráyà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Kéde lẹ́ẹ̀kan sí i pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ìwà rere máa pa dà kún àkúnwọ́sílẹ̀ ní àwọn ìlú mi; Jèhófà yóò sì pa dà tu Síónì nínú,+ yóò sì tún Jerúsálẹ́mù yàn.”’”+
17 “Kéde lẹ́ẹ̀kan sí i pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ìwà rere máa pa dà kún àkúnwọ́sílẹ̀ ní àwọn ìlú mi; Jèhófà yóò sì pa dà tu Síónì nínú,+ yóò sì tún Jerúsálẹ́mù yàn.”’”+