ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 132:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nítorí Jèhófà ti yan Síónì;+

      Ó fẹ́ kó jẹ́ ibùgbé rẹ̀, ó ní:+

  • Sekaráyà 2:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Jèhófà yóò gba Júdà bí ìpín rẹ̀ lórí ilẹ̀ mímọ́, yóò sì tún Jerúsálẹ́mù yàn.+

  • Sekaráyà 3:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Áńgẹ́lì Jèhófà wá sọ fún Sátánì pé: “Kí Jèhófà bá ọ wí, ìwọ Sátánì,+ bẹ́ẹ̀ ni, kí Jèhófà, ẹni tó yan Jerúsálẹ́mù+ bá ọ wí! Ṣebí ẹni yìí ni igi tó ń jó tí wọ́n yọ kúrò nínú iná?”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́