-
Jeremáyà 48:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Àwọn ọ̀mùnú rẹ tó yọ ti sọdá òkun.
Wọ́n ti dé òkun, wọ́n sì ti dé Jásérì.
Apanirun ti balẹ̀+
Sórí èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn rẹ àti èso àjàrà tí o kó jọ.
-