-
Àìsáyà 16:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Torí àwọn ilẹ̀ onípele Hẹ́ṣíbónì+ ti gbẹ,
Àjàrà Síbúmà,+
Àwọn alákòóso àwọn orílẹ̀-èdè ti tẹ àwọn ẹ̀ka rẹ̀ tó pupa fòò* mọ́lẹ̀;
Wọ́n ti lọ títí dé Jásérì;+
Wọ́n ti tàn dé aginjù.
Àwọn ọ̀mùnú rẹ̀ ti tàn kálẹ̀, wọ́n sì ti lọ títí dé òkun.
9 Ìdí nìyẹn tí màá fi sunkún torí àjàrà Síbúmà bí mo ṣe ń sunkún torí Jásérì.
-
-
Jeremáyà 48:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Apanirun máa wá sórí gbogbo ìlú,
Ìlú kankan ò sì ní yè bọ́.+
-