ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 25:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí ọwọ́ Jèhófà máa wà lórí òkè yìí,+

      A sì máa tẹ Móábù mọ́lẹ̀ ní àyè rẹ̀+

      Bíi pòròpórò tí wọ́n tẹ̀ mọ́ inú ajílẹ̀ tí wọ́n kó jọ.

  • Jeremáyà 48:46, 47
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 ‘O gbé! Ìwọ Móábù.

      Àwọn èèyàn Kémóṣì+ ti ṣègbé.

      Nítorí a ti mú àwọn ọmọkùnrin rẹ lẹ́rú,

      Àwọn ọmọbìnrin rẹ sì ti lọ sí ìgbèkùn.+

      47 Ṣùgbọ́n màá kó àwọn ará Móábù tó wà lóko ẹrú jọ ní ọjọ́ ìkẹyìn,’ ni Jèhófà wí.

      ‘Ibí ni ìdájọ́ Móábù parí sí.’”+

  • Sefanáyà 2:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Nítorí náà, bí mo ti wà láàyè,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí,

      “Móábù máa dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,+

      Àti àwọn ọmọ Ámónì bíi Gòmórà,+

      Ibi tí èsìsì wà, tí kòtò iyọ̀ wà, tó sì ti di ahoro títí láé.+

      Àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn mi á kó wọn lọ,

      Àwọn tó ṣẹ́ kù nínú orílẹ̀-èdè mi á sì gba tọwọ́ wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́