-
Jeremáyà 48:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nítorí o gbẹ́kẹ̀ lé iṣẹ́ rẹ àti àwọn ìṣúra rẹ,
A ó mú ìwọ náà lẹ́rú.
Kémóṣì+ máa lọ sí ìgbèkùn,
Pẹ̀lú àwọn àlùfáà rẹ̀ àti àwọn ìjòyè rẹ̀.
-