Diutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+ 2 Sámúẹ́lì 22:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ta ni Ọlọ́run bí kò ṣe Jèhófà?+ Ta sì ni àpáta bí kò ṣe Ọlọ́run wa?+
4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+