-
Diutarónómì 28:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 “Tí o bá ń pa gbogbo àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ tí mò ń pa fún ọ lónìí mọ́ délẹ̀délẹ̀, kí o lè máa rí i pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, ó dájú pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa gbé ọ ga ju gbogbo orílẹ̀-èdè yòókù tó wà láyé+ lọ. 2 Gbogbo ìbùkún yìí máa jẹ́ tìrẹ, ó sì máa bá ọ,+ torí pé ò ń fetí sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run rẹ:
-
-
Jóẹ́lì 2:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Jèhófà yóò dá àwọn èèyàn rẹ̀ lóhùn pé:
-